Àjọ tó ń rísí ìṣọ̀kan àgbáyé, UN rọ Nàìjíríà Láti Ṣe ìmúlò àbájáde Ìgbìmọ̀…
Àjọ UN ti késí Ìjọba Nàìjíríà láti ṣe ìmúlò ìmọ̀ràn Ìgbìmọ̀ Ìwádìí ìdájọ́ àti àtúnṣe tí wọ́n gbékalẹ̀ láti ṣe ìwádìí àwọn ọ̀ràn tí ó jẹyọ lórí ìfẹ̀hónúhàn #EndSARS ọdún 2020.
Alukoro UN ati…