U20 AFCON 2023: Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Gbà Flying Eagles Níyànjú Láti Gbé Ìfé Náà Wálé
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí gbà àwọn àgbábọ́ọ̀lù Flying Eagles níyànjú láti gbà ìfé ìdíje CAF U-20 Africa Cup of Nations (AFCON) tó ń lọ lọ́wọ́ ní Egypt.
Flying Eagle yóò kojú Gambia lóni ní ìpele aṣekagba tí ìdíje náà pẹ̀lú bí wọ́n tí ṣé…