Ààrẹ Egypt, EU ṣe ìjíròrò lórí làásígbò ìrànlọ́wọ́ Gaza
Ààrẹ ìgbìmọ̀ Yúróópù, Ursula von der Leyen ti sọ pé òun kò lọ́wọ́ sí “ṣíṣí àwọn ọmọ Palestine nípò padà pẹ̀lú ipá” lásìkò ìpàdé kan ní Cairo pẹ̀lú ààrẹ Egypt, Abdel Fattah al-Sisi.
Von der Leyen wa dupẹ…