Ààrẹ bìnrin àkọ́kọ́ Tanzania ṣàbẹ̀wò sí orílẹ̀-èdè South African
Ààrẹ oriĺẹ̀-èdèTanzania Saluhu Hassan, ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ètò ààbò àti kár̀a kátà pẹ̀lú South Africa.
Hassan, ààrẹ bìnrinTanzania àkọ́kọ́ , ṣèpàdé pẹ̀lú ààrẹ orílẹ̀ -èdè South African, Cyril…