Ẹ MỌ́KÀNLE NÍNÚ ÌPỌ́NJÚ- Ọ̀JỌ̀GBỌ́N OSINBAJO
igbákejì ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, ọjọgbọn Yemi Osinbajo ti rọ àwọn adarí láti mọ́kànle nínú ìpọ́njú tàbí ìpèníjà tí wọ́n bá ń dojúkọ kí wọ́n leè jẹ́ àwọkọ́se rere fún àwọn ti wọ́n ń darí.
Osinbajo …