Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara Ki Àwọn Ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí Kú Òngbẹ.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara Abdul Rahman AbdulRazaq ti darapọ̀ mọ́ àgbáyé láti kí àwọn ẹlẹṣin Mùsùlùmí Kú amojuba oṣù Àwẹ̀ Ramadan, o wa gbàdúrà fún àlàáfíà pípé láti parí rẹ.
Nínú ọ̀rọ̀ àtẹ̀jade kan láti ọwọ́ Akọ̀wé fún Gómìnà Rafiu Ajakaye,…