Burna Boy, Tems Wa Lára Àwọn Ọgọ̀rún Olórin Tó Dára Jùlọ Bí New African Magazine Se Gbekalẹ̀
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ Nàìjíríà ló wa ní ipò òkè bi New African Magazine se gbèe ogorun oruko awon olórin tó lààmì laaka ni ilẹ̀ Adulawọ ti ọdún 2023 jáde.
Ìwé ìròyìn náà gbé ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn jáde lati eka bíi oselu, ilé iṣẹ,…