Àwọn ènìyàn márùnlé-lọ́gọ́fà ènìyàn míràn ló tún ti kó ààrùn covid jákèjádò orílẹ̀-èdè lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìi.́Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní Nàìjíríà (NCDC) ló kéde eléyìí.Awọn eniyan wọnyi jẹyọ lati ipinlẹ mẹwa gẹgẹ bi ile-iṣẹ naa ṣe fi to wa leti.
Olu-ilu-(marunle-logoji) ,Kaduna (mẹrinle-lọgbọn),Rivers (mọkanla),Lagos (mẹwa ),Ọsun (mẹwa),Ọyọ (mẹsan ),Jigawa (meji), Ẹdo (meji), Kano (meji ),Plateau(ẹyọkan). Lọwọlọwọ bayii, eniyan ẹẹdẹgbarun-le-ni-ọkẹ-mẹwa-o-le-ni-eji-din-lọọdunrun loti ko aarun covid,ti ẹte-din-ni-oji-le-lẹgbẹẹrinla ti jẹpẹ oluwa.
Leave a Reply