Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Onísòwò Ṣàgbékalẹ̀ Ohun èlò ibara-ẹni-sọrọ Tí yóò Dènà àwọn Ajínigbé Ní DR Congo

0 353

Àwọn obínrin onísòwò méji ní Democratic Republic ti Congo ti ṣe àgbékalẹ̀ ohun èlò ibanisọrọ alágbéká kan tí ó ṣe ìrànlọ́wọ́ fún líló ọkọ́ ayọkẹlẹ láìsí ewu

Ursula Ndombele ati Magalie Bueyasadila seda ‘Hoja app’ ti o n ṣe iranlọwọ fun eniyan lati mọ nipa awakọ wọn.

Ọpọlọpọ awọn awakọ Kinshasa ti forukọsilẹ  ati pe wọn sọ pe “o dara fun ìṣòwò bi awọn onibara ṣe gbẹkẹle wọn sii.”

 

Tolulope Akinseye

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button