Máa bá isẹ́ rẹ lọ,ààrẹ Buhari tún yan Milland Dikio padà fún ìgbàkejì

Aarẹ orilẹ ede Naijiria , Muhammadu Buhari  tun ti fọwọsi ọdun kan fun igba keji miran  fun  yiyan alakoso fidiẹ fun eto iranwọ ijọba apapọ fun awọn to gba aforiji .

Wọn yan Dikio  gẹgẹ bi alakoso  fidiẹ ni osu kẹjo , ọdún 2020,.Lasiko ti alako de ipo rẹ ni o ti yanju awọn isoro to n dojukọ  ajọ  Niger Delta.

Oloogbe aarẹ Umaru YarÁdua lo da ajọ  2009, eto iranwọ ijọba apapọ fun awọn to gba aforiji silẹ lati maa setọju awọn ajijagbara  ti ẹkun Niger-Delta lasiko ti wọn fi iwa ipá wọn silẹ.

 

Amnesty Programme: President Buhari Renews Interim Administrator’s Appointment
Comments (0)
Add Comment