Take a fresh look at your lifestyle.

Fidio:Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara fárígá bí ọ̀gá ilé-ẹ̀kọ́ Arabic se na akẹ́kọ̀ọ́,ló bá gbé ìwé jókòó,sílé fún un

0 257

Aṣoju kan lati Ijọba ipinlẹ Kwara ti ṣabẹwo si ile -ẹkọ Arabic, nibi ti , ọga ile-ẹkọ ọhun ti na akẹkọọ kan ti wọn fi ẹsun kan pe , o hu iwa ibajẹ, ni eyi ti fọnran aworan naa si ti gbode kan .

Ijọba si ti yan awọn igbimọ iwadii  lori isẹlẹ ọhun , lara wọn  ni awọn onimọ ninu ẹsin islam , awọn oludari oṣiṣẹ ijọba.

Bakan naa, ni ijọba tun ti gbe gbogbo awọn ọmọ ile –iwe ọhun lọ si ile -iwosan  fun itọju ayẹwo  ati itọju to peye.

Ijoba wa rọ gbogbo s awọn ọmọ ipinlẹ ọhun lati  ni suurun titi ti  igbimọ naa yoo fi p pari isẹ́ iwadii wọn.

 

Olufunmi ati Bankọle

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button