Take a fresh look at your lifestyle.

A o parí àwọn isẹ akanse ko to di ọdun 2023- Aarẹ Buhari

0 274

Aarẹ Muhammadu Buhari ti fi ara-ilu Naijiria lọkan balẹ pẹ isẹ akansẹ ori afara keji to wa ni Niger, ipinlẹ Eko si ilu Ibadan ti ijọba apapọ dawọ le ni wọn yoo pari ki ijọba yii to pari saa keji ti wọn gùnlé.

Aarẹ  sọrọ yii lọjọ Aje lasiko ti wọn n se  igbeyẹwo awọn  aseyọri isẹ akanse ti ijọba rẹ ti se lati igba ti o ti wa n i ijọba.

 

ṣalaye bi inu oun se dun si awọn minisita to n jabọ yii lasiko ti  Igbimọ ijọba apapọ n salaye aseyọri ti wọn ti se lati ọdun meji sẹyin ti wọn ti ninu ijọba rẹ.

Aarẹ tun tẹsiwaju pe ọpọlọpọ aseyọri miran ni ijọba rẹ ti se paapaa julọ nipa ọkọ oju irin  lorilẹ ede Naijiria.

O tun sọ pe ijọba rẹ ko ni kaare lati tun tẹpẹlẹ mọ eto aabo, ẹka amusagbara ati idagbasoke lori ironilagbara fun awọn ọdọ.

 

 

Bankọle ati Olufunmi

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button