Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdùnnú subú layọ̀! Ìtọ́jú ti wà fún àwọn tó nì àrùn jẹjẹrẹ

0 385

Oludari ile akede Naijiria,( Voice of Nigeria, VON), Osita Okechukwu  ti sapejuwe ile -itọju  arun jẹjẹrẹ ti wọn kọ si ipinlẹ Kano gẹgẹ bi eto iranwọ  fun awọn to ba ni arun ọhun..

O tẹsiwaju pe ierti ti wa bayii fun itọju arun gbẹ̀mí-gbẹ̀mí jẹjẹrẹ lẹyin itọju arun ọhun ni ile-iwosan naa.

Osita se alaye  yii lasiko irinajo ti gomina ipinlẹ Kano seto fun  ẹgbe awọn oludari ile isẹ redio ati mohun-maworan lorilẹ ede  Naijiria ,lasiko ipade apero ọlọdọọdun ti wọn maa n se, ni eyi to waye ni ipinlẹ Kano.

o tun sọ pe saaju asiko yii ni arun jẹjẹrẹ ti maa n gbẹmi ọmọde ati agbalagba , ti o si jẹ pe arun yii ti sọ abiku di oloogun èké nitori pe ko see tọju.Amọsa pẹlu ile-iwosan fun itọje arun jẹjẹrẹ ti ijọba ipinlẹ Kano kọ yii, o daju pe ireti ti wa fun awọn to ba ni arun jẹjẹrẹ lorilẹ ede Naijiria.

Osita wa gbosuba fun ijọba ipinlẹ Kano fun gudu gudu meje yaya mẹfa ti wọn se

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button