UNGA: Ààrẹ Bùhárí gúnlẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, New York

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Ààre Mùhámmádù Bùhárí gúnlẹ̀ sí ìlú New York, láti kópa nínú ìpàdé keje ti Àpèjọ Gbogbogbò, ti Àjo Àgbáyé (UNGA 76).

Aarẹ gunlẹ ni deede agogo mẹjọ aabọ owurọ.

Aarẹ Buhari yoo ba UNGA 76 sọrọ, ni ọjọ ẹti, oṣu kẹsan ọjọ kẹrinle-logun.

Apejọ Gbogbogbo  Ajo Agbaye jẹ apejọ ọlọdọọdun ti awọn olori orilẹ-ede maan ṣe, nibiti wọn  ti  maa n jiroro lori awọn ọrọ to ṣe pataki nipa idagbasoke ọmọniyan.

 

New YorkUNGA: Ààrẹ Bùhárí gúnlẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Comments (0)
Add Comment