Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Ènìyàn méjì -dín – làádọ́sàn án míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 347

Ní ọjọ́ kọkàndín-lógún, oṣù kẹsàn-án ọdún 2021,ènìyàn méjì-dín-láàdọ́sàn míràn tún ti ní ààrùn covid,tí ẹnìkan sì j’ọ́lọ́run nípè, gẹ́gẹ́ bí ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè (NCDC ).

Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbàá- le- lọ̀kẹ́ mẹ̀wá – din – lèjì lo ti ko aarun ọhun,eniyan ẹgbẹ́rún- le-  lọ̀kẹ́ mẹ̀sán abo – din ni- ẹ̀ta- din– loojì ti gba iwosan, ti eniyan mẹ́ẹdógún-din-ni-ọ́ta- din-  lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ẹ̀rinlá si ti jẹpe oluwa ni ipinlẹ mẹrindin-logoji ati olu ilu.

Awọn eniyan meji-din-laadọsan an ọhun wa lati ipinlẹ mọkanla – Lagos (marun-din-lọgọrin ),Abia (merin-din-lọgbọn ), Niger (ogun ) ,Olu-ilu (mẹedogun ),Benue (mẹjọ ),Ogun (mejọ ), Ọsun (meje ),Ẹdo (mẹta) Kaduna (meji ), Kano (meji ),Ondo (meji ).

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button