Ènìyàn méje míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Ilé-iṣẹ́ tó ńmójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, sọ pé ènìyàn méje tún ti ní ààrùn covid ní ọjọ́ àìkú.
Ni bayii,eniyan marun le-lọgọta ẹgbẹrun , ati ẹdẹgbẹrin le mẹsan ti ni aarun covid,ẹẹrin din –lọgọta ẹgbẹrun ati ẹẹtala-lenirinwo irinwo eniyan ni oti riwosan, ti ẹgbẹrun meji ati ẹẹrin-din-laadọrin si ti jẹpe oluwa.
Niger-márùún, Rivers-méjì.

Ènìyàn méje míràn tún ti ní ààrùn covid
Comments (0)
Add Comment