Ẹ ò tó, ẹ lọ pọ̀ si wá:Chelsea gé ìyẹ́ apá Man City nínú àṣekágbá Champions League
Ademọla Adepọju
Lọ́jọ́ Àbámẹ́ta yìí ni ikọ̀ agbabọọlu Chelsea kó pàsán ìyà lu ikọ̀ Manchester City , nínú ìdíje bọ́ọ̀lú à-fẹsẹ̀gbá tó wáyé ní pápá ìṣeré Etihad.
Ìyà ẹgba meji (2) pere ni ikọ̀ agbabọọlu Chelsea fun ikọ̀ agbabọọlu Manchester City, ti ikọ agbabọọlu Chelsea naa si fara káásá iya ẹgba kan(1) , sé ìyà díẹ̀-díẹ̀ ló ń jòkú ìgbẹ́
Amọsa, ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu karun un ní wọn mejeeji yoo pade ninu ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Champions League.
Ademọla Adepọju
Leave a Reply