Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano Ṣe Iranlọwọ Owò Fún Àwọn Obínrin Láti Bẹ́rẹ Okòwò

4,618

Gómìnà ìpínlẹ̀ kano, Kabir Yusuf ti fún àwọn Obìnrin ìpínlẹ̀ náà ni ẹgbẹrun Náírà láti fi bere òkòwò.

Ó ní èyí yóó mu ki òsì ati ìyà dì kun ni ìpínlẹ̀ náà láàrin àwọn Obìnrin

Nínú àtẹ̀jáde láti ọwọ̀ agbẹnusọ fún Gómìnà Sanusi Bature ni ọ̀rọ̀ náà ti di mímọ̀ nìgbà ti wọn se iranlowo fún àwọn ènìyàn.

Ó ni lára ìlérí ti Gómìnà ṣe lásìkò ìdìbò re ni ó ń muse  láti mu inú àwọn ènìyàn dùn, Gómìnà ṣe Ileri wí pè ọdun 2026 yóó je ọdun ti yóò dènà ìsẹ́ ati òsì ni ìpínlẹ̀ náà.

Ó ni yatọ sí  àwọn ènìyàn ti jẹ anfààní lọ́wọ́  báyìí ọpọlọpọ ìgbà ni àwọn ènìyàn ti  jẹ anfààní láti ọ̀dọ Gómìnà lásìkò ti o wa lórí ipo

Ó wa rọ àwọn to jẹ anfààní náà láti lò ni ọna ti yóò mú ìwúrí wa, ati fún ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀ náà.

Comments are closed.

button