Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà Ṣé ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ Ológun Israel

Lekan Orenuga

111

Ilé-iṣẹ́ tí Ààbò tí tún fí hàn pé ìjọba Nàìjíríà ìtẹ̀síwájú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ilé-iṣẹ́ ológun rẹ̀ pẹlú tí Orílẹ̀-èdè Israel.

‎ Akọwe àgbà tí Ilé-iṣẹ́ ológun náà, Gabriel Aduda, tó pàdé pẹ̀lú Aṣojú Israeli sí Nàìjíríà, Michael Freeman, l’àkókò ibẹwo rẹ̀ sí Ilé-iṣẹ́ ológun náà ní olú-ìlú Nàìjíríà ní Abuja, Ó ṣàfihàn nínú ọrọ kán pé àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì tí jíròrò àwọn ọnà sí ìdàgbàsókè ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ààbò.

‎ O ṣé àfihàn ìwúlò látí jindo sínú àwọn àsopọ ààbò náà látí le jẹ́ kí ìdàgbàsókè túbọ̀ bá ètò ààbò lágbayé.

‎ Freeman tẹnumọ pàtàkì tí àjọṣepọ̀ náà gẹ́gẹ́bí ìgbésẹ̀ ìlọsíwájú, ó sí rọ́ Ilé-iṣẹ́ Ààbò tí Nàìjíríà láti ṣé àbẹwò sí Orílẹ̀-èdè Israeli láti tún mú ìbátan láàrin àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì pọ sí.

Comments are closed.

button