Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ní Ìpínlẹ̀ Kwara tí takò àtẹ̀jáde kán tó níí ṣé pẹ̀lú ẹsùn ìkọlù kán tí wọ́n ní àwọn agbesunmọmi kán tí orúkọ wọ́n njẹ́ Mahmuda láàrin ìjọba ìbílẹ̀ Kaiama ati Baruten ní ìpínlẹ̀ Kwara.
Nínú àlàyé kán látí ẹnu Aláṣẹ Ìbáṣepọ̀ Aráàlú àti ọlọ́pàá, SP Adetoun Ejire-Adeyemi èyí tó sọ pé ọlọ́pàá ọtẹlẹmuyẹ àti awọn irọkẹ̀kẹ ewu, ìwòyè, àti àwọn oníṣẹ́ ọgbọ́n ní àwọn agbègbè wọ̀nyí kò rí ẹrí kán lórí iṣẹlẹ ipanilaya ni agbègbè náà.
O sọ pé otu bantẹ lásán ní ìròyìn pé wọ́n pá àwọn aṣọde mẹẹdogun (15 vigilantes).
Àlàyé náà fí dá àwọn aráàlú lójú pé gbogbo ètò ààbò ìpínlẹ̀ náà ló wà ní bó tí yẹ.
Comments are closed.