Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Ilé Iṣé Aláàdáni Yóò Ni Ìbáṣepọ̀ Láti Mú Ìdàgbàsókè Ba Ilé Ìwòsàn Ìjọba.
Ìjọba àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí buwolu ìwé ìbáṣepọ̀ láàrin ilé ìwòsan ìjọba National Hospital ti Abuja àti ilé ìwòsan aláàdáni merin míràn láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ìlera Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Nígbà tí o n sọrọ níbi ayẹyẹ náà Mínísítà fún ètò ìlera àti ìtọ́jú àwọn ènìyàn, Ọ̀mọ̀wé Muhammad Ali pate, so wí pé ìbáṣepọ̀ náà yóò mú kí àwọn òṣìṣẹ́ tubọ ni imọ lori iṣé wọn ki ìdàgbàsókè baa le ba ètò ìlera.
Àwọn ti wọn bá ní ìbáṣepọ̀ náà ni
Fásítì Nile
Fásítì Comospolitan,
Fásítì Yangongwo
Ilé ilé ètò ìwòsàn àti Medix foundation ti Orílẹ-èdè Nàìjíríà àti òkè òkun.
Wọn ní ìbáṣepọ̀ náà yóò mú àlàáfíà àti ìdàgbàsókè ba ètò ìlera