Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Akẹẹkọ Tó Ti Pegedé Láti Ilé Èkó Poly- Technic  Fún ( HND) Ni Ó Ní Ẹtọ Láti Tèsíwájú Fún Ètò Agunbaniro: Mínísítà Jack Acheme.

57

Mínísítà fún ètò ẹkọ, Maruff Olatunji Alausa ti Kede wí pé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti ko fi ọjọ kan sílẹ fún ètò ẹkọ HND ni kan ni o ní ètò láti ṣe agunbánirò ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ so fún àwọn oníròyìn láti ẹnu Boriowo Folashade tó jẹ adarí fún ètò ìròyìn, so di mímọ̀ wí pé àtúnṣe yìí wáyé lẹyìn ìgbà ti ìpàdé wáyé láàrín adari àgbà pátápátá fún ètò àgùnbánirọ̀.

Alausa ní o ti di ofin báyìí wí pé àwọn tó kàwé gbà iwe HND Lai sí àlàfo nínú rẹ lásìkò ètò ẹ̀kọ́ náà ni ó ní anfààní láti ló ṣe àgùnbánirọ̀.

Mínísítà wa rọ wọn láti lò anfààní náà dáradára lásìkò yìí.

Comments are closed.

button