Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu ṣe pàdé pẹ̀lú Ọba Asagba ti Asaba, tó jẹ ọba ìpínlẹ̀ Delta, Ọ̀mọ̀wé Obi Epiphany Azinge ní ìlú ilé ìjọba ni ìlú Abuja.
Ní ọ̀jọ́bo ni Ààre àti Ọba pàdé ní ilé ìjọba ni ìlú Òṣìṣẹ́ ìjọba legbe rẹ.
Èyí jẹ ìbẹ̀wọ̀ àkókò ti Ọba Asagba ti Asaba yóò ṣe sí Ààre Tinubu láti ti igba ti o ti gorí ipò àwọn bàbá rè gégé bí Oba kẹrinla.