Take a fresh look at your lifestyle.

Eré Ìjàkadì ECOWAS A Má Fa Àjosepọ̀ A Má Ró Àwọn Ọ̀dọ́ Lágbára

134

 

Àjọ Economic Community of West African States(ECOWAS)
ti fún ECOWAS African Wrestling Tournament (TOLAC) ẹlẹ́kẹtàlá irú rè ni máákì tó yanrantí wípé ó jẹ́ ọ̀nà ti àjọ náà fí máa ń wà kí àjosepọ̀ kí o wà ní gbogbo àgbègbè, a sì tun máa ro awon ọ̀dọ́ lágbára pẹ̀lú ibuyi kùn àsà.

Wọ́n sọ èyí níbi ẹyẹ àsekágbá ìdíje ẹkẹ mímù ní pápá isere Velodrome, Moshood Abiola ní ìlú Abuja, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ikọ̀ ti orílẹ̀-èdè Senegal ló ṣe ipò kinni, orílè-èdè Naijiria ṣe ipò Kejì, orílè-èdè Benin wà ní ipò kẹta nínú idije náà bí àjọ ECOWAS se sọ.

Ìdíje náà jẹ́ èyí tí w6ọn fi n sàmì sí ayẹyẹ àjọ ECOWAS tí wọn pé ọmọ Àádọta ọdún . Eléyìí ti wá jẹ́ kí ìfẹ́ kí o wà ninú eré ìdárayá, ó tún so ilẹ̀ Adúláwọ̀ papọ̀ nínú ìfẹ́ àti àjọṣepọ̀ tó múyán lórí.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button