Take a fresh look at your lifestyle.

Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Kwara United Gbo Ewúro Sí Ojúgbà Rẹ̀ El-Kanemi Lójú Pẹ̀lú Àmì Ayò Méjì Sí Òdo

113

Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Kwara United fi àgbà han ikọ̀ ti El-Kanemi nígbà tí ó jáwé olúborí pẹ̀lú àmì ayò méjì sí òdo, níbi ìfẹsẹ̀-wọnsẹ̀ tí ó wáyé ní pápá eré ìdárayá Rasidi Yẹkini, èyí tí ó wà ní ìlú Ilọrin, Ìpínlẹ̀ Kwara

 

Ìfẹsẹ̀wọnṣẹ̀ náà gbóná jan-jan, sùgbọ́n lẹ́yìn-ò-rẹyìn, ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù El-Kanemi fìdí rẹmi, nítorípé bí irin bá kan irin, ọ̀kan a tẹ̀ fún ìkejì

 

Wasiu Alalade ni ó jẹ àmì ayò àkọ́kọ́ fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Kwara United, nígbà tí Wasiu Jimọh jẹ àmì ayò ẹlẹ́ẹ̀kejì ní ìpínkejì eré ìdárayá náà

 

 

Comments are closed.

button