Wọ́n ti pín ikọ̀ Nàìjíríà Super Eagles B pẹ̀lú àwọn ikọ̀ Senegal, Sudan àti Congo Brazzaville sí ìsòrí “D” ti ìdíje ẹlẹ́kejọ irú rẹ̀ – 8th African Nations Championship (CHAN).
Ìdíje náà ni wọ́n ti sún síwájú sí oṣù kẹjọ ọdún yìí ṣùgbọ́n àwọn olùgbàlejò ìdíje náà , Tanzania, Kenya ati Uganda sí wà bẹ́ẹ̀.
Bí àwọn olùkópa se wà ní Ìsòrí nìyí:
Ìsòrí A: Kenya, Morocco, Angola, DR Congo, Zambia.
Ìsòrí B: Tanzania, Madagascar, Mauritania, Burkina Faso, Central African Republic.
Ìsòrí C: Uganda, Niger Republic, Guinea, Wild Card 2, Wild Card 1.
Ìsòrí D: Senegal, Congo Brazzaville, Sudan, Nigeria.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san.