Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Gómìnà Láti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Péjú Síbi Ayẹyẹ Ìbúrasípò Ààrẹ Tí Wọ́n Dìbòyà Ní Orílẹ̀-èdè Ghana

130

Gómìnà márùn-ún ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ó ti gúnlẹ̀ sí ìlú Accra láti kópa níbi ayẹyẹ ìbúrasípò ààrẹ tí wọ́n dìbòyàn, John Dramani Mahama èyí tí yóò wáyé ní ọjọ́ ìṣẹ́gun ní gbọ̀ngàn Black Star, Ilu Accra

 

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Adamawa, Ahmed Fintiri pẹ̀lú ojúgbà rẹ̀ ti ìpínlẹ̀ Taraba, Zamfara, Plateau, ati Delta ni Ààrẹ tí wọ́n dìbòyàn fìwépè, èyí tí wọ́n sèpàdépọ̀ ní ọjọ́ ajé lórí àwọn ọ̀rọ̀ pàtàkì síwájú ayẹyẹ ìbúrasípò

 

Ayẹyẹ ìbúrasípò náà yóò làmì-laaka tí yóò sì jẹ́ ohun málegbàgbé nígbà tí Mahama yóò padàsípò lẹ́yìn ọdún mẹ́jọ tí agbára ti bọ́ nih ọwọ́ ‘rẹ̀

Comments are closed.

button