Òṣèré Charles Okocha ti se afihan aya afesona rẹ̀ , o sí ti da ọjọ Ìgbeyàwó sọ́nà báyìí.
O se eleyii lórí òpò èrò ayelujara Instagramu rẹ níbi to ti se àfihàn orísìí fọ́tò àwọn méjèèjì tó rẹwà tó sì fi ifẹ han
pé wọ́n ti ṣetán ìgbeyàwó pẹ̀lú -“#MICHARLES2024” .
Okocha fẹ́ràn láti ma se àfihàn ara rẹ̀ àti ipò pàtàkì tó kò nínú eré, eléyìí tó se yìí ti jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olólùfẹ́ rẹ̀ nìfẹ́ láti wá síbi ètò ìgbéyàwó rẹ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san