Olubori ìdíje nígbà kàn ati olukọ orin sílẹ ati akorin, Ayra Starr ńtàn bi Imọlẹ níbí ìdíje orin – Coldplay’s sold out concert ti ọdún 2024 Coldplay’s Music of the Spheres 2024 World Tour. Akọrin lati orilẹ-ede Australia , New Zealand ati káàkiri ayé wa nibẹ̀. Fún àpẹrẹ ,Zimbabwe – Shone ati Australia- akorin Emmanuel Kelly.
.
Coldplay ti lo akọrin Ayra Starr níbi orin rẹ to n gbóná fẹlifẹli bíi; ‘Moon Music’ ni ti Tiraki ‘Good Feeling’ .
Olorin ìràwọ̀ Pop náà Ayra Starr jẹ́ obinrin Nàìjíríà akọkọ ti wọn yàn fun ẹbùn “Grammy” pẹlu orin rẹ̀ to pè ni- ‘The Year I Turned 21’ to se afihan ìràwọ olorin bii Asake ati Seyi Vibez, ìràwọ akorin ilu American RnB :Giveon àti Coco Jones, ati ti orílẹ-èdè Brazil- hitmaker Aniita.
Ayra Starr ni wọ́n yàn ni àìpẹ yi fún ìdíje
MTV EMAs, ọdún 2024 fun – “Best New Artist àti Best Afrobeats” tó wáyé ni ọjọ́ kẹwàá, oṣù kọkànlá ni ilú Manchester.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san