Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara AbdulRahman Abdulrazak ti Buwọ́lù àfikún owó fún àwọn òṣìṣẹ́ ìpínlẹ̀ náà pátá pátá.
Ó ní láti fi di àwọn àfikún owó ẹyin tó yẹ ki ijoba san fún àwọn òṣìṣẹ́ ni oun se Buwọ́lù lu ìwé náà àti láti mú inú àwọn òṣìṣẹ́ dun gidigidi.
Wọn ní ètò owó ṣiṣan náà yóò wáyé láti oṣù kẹwàá titi di oṣù Kejìlá oṣù. 2024 eyin fi hàn wí pé Gómìnà fẹràn awọn òṣìṣẹ́ rẹ lọ́pọ̀lọpọ̀.
Nínú atejade lati owó ijoba ìpínlẹ̀ Kwara, o sọ wí pé òṣìṣẹ́ ti ko bá ti fi orúkọ rẹ sílẹ labẹ ilé iṣé ijoba (KWSRRA) kí ọ tètè lọ fi sílẹ nítorí pé ìjọba ko ni san owó fún òṣìṣẹ́ ti ko ba fi orúkọ rẹ silẹ.