Mínísítà àná fún Ètò Ìrìnàjò àti Ìgbafẹ́
Iyaafin Lola Ade-John ti dupẹ lọwọ Ààrẹ Bola Tinubu fún Òòrè Ọfẹ láti sin Orilẹ-ede Nàìjíríà.
Iyaafin Ade-John fi ìdùnnú rẹ hàn sí ààrẹ ninu leta jànràn tó kọ ni ọjọ Ẹtì láti dúpẹ fun oore ọfẹ láti sìn ilu.
Olùrànlọ́wọ́ rẹ n’ípa ti ìròyìn, Elizabeth Ofili.ló gbe lẹta náà sita fún.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san