Take a fresh look at your lifestyle.

Amẹ́ríkà Buwọ́lu Bílíọ̀nù Méjì Dọ́là Ohun Ìjà Ogun Títà Fún Ilẹ̀ Taiwan

151

 

Orilẹ-ede Amerika Buwolu Biliọnu Meji Dola Ohun Ìjà Ogun Tita Fún Ile Taiwan, Ile igbimọ Pentagonso èyí ni ọjọ Ẹti.

Ofin De Orilẹ-ede Amerika láti pèsè ohun ìjà ogun fún Taiwan ti ile China gba lati dáàbò bo ara rẹ.

Ijoba ile China se ikọlu sí ilé Lai ni ọjọ Abameta, wọn ṣì sẹ́ ọrọ ti wọ́n so ni ọjọ Ẹti pé kosi ogun àtìtawá kankan to lee yi ọjọ ọla ilẹ̀ Taiwan padà.

” Koni sí ọjọ ọla fún òmìnira ile Taiwan ‘. Ọjọ ọla ilẹ̀ Taiwan wá lọwọ iṣọkan ilẹ̀ ibí wọn,” – Ofiisi China’s Taiwan Affairs .

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button