Ilẹ̀ Iran ti bẹ enu ate tuntun lu ilẹ EU àti Geesi ti wọn gbe lé ilẹ̀ Tehran wọn si tun sẹ́ pe awon ko pèsè ado o weloro fún ilẹ̀ Russia,.
Ajọ iṣọkan agbaye pinu ni ojó ajé lati gbe òté le àwọn ènìyàn ati àjọ meje kan
pelu airline Iran Air, fún ajọṣepọ gbigbe ado oloro lọ sí ilẹ̀ Russia.
Àwọn to tun wa níbẹ̀ ni Saha Airlines ati Mahan Air ati igbakeji mínísítà ètò aabo ilẹ̀ Iran, Seyed Hamzeh Ghalandari.
Baghaei bu enu ete lu ote tuntun náà lati ọwó ajọ isokan agbaye ati UK, pé o lodi si ofin agbaye .
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san