Ayò Kan Dondo ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀKÓKÓ INÚ ÌRÒYÌNÓ GBÓNÁ FẸLI-FẸLI By Temitope Emmanuel On Oct 11, 2024 169 Share Ní ìparí ìfagagbága òní, ikọ̀ orilẹ̀-ède Nàìjíríà gbo ewúro sójú alátakò wọn Libya pẹ̀lú ayò ẹyọkan dondo láti ẹsẹ̀ Ògbótàrigì atamátàsé, Fisayo Dele-Bashiru ní ìlú Uyo. Naijiria 🇳🇬 1-0 Libya 🇱🇾. Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san 169 Share FacebookTwitterWhatsAppEmailLinkedinTelegram