Gbajugbaja Òṣèré Tíátà ni, ti gbogbo àwọn ènìyàn mọ sí Ọgbẹni Ibu ti saye sílẹ̀.
Òṣèré apanilẹ́ẹ̀rín náà ní o jáde láyè ni ọjọ́ Kejì oṣù kẹta ọdún 2024, ni ilé ìwòsàn Evercare to ni ìlú Eko.
Lati bi ọdún diẹ sẹyìn ni gbajugbaja Òṣèré Tíátà náà ti n kojú àìsàn tó n ba ẹjẹ já, èyí tó mú kí wọ́n gé ẹsẹ rẹ.
Ẹni ọdún méjìlèláàgóta ni .
O sí ti kópa nínú àwọn iṣé lorisirisi ní èyí tí àgbáyé fi dá mọ.