Take a fresh look at your lifestyle.

Ìyí Kòtò Fún Ìbẹ̀rẹ̀ Ìdíje AFCON 2025 Yóò Wáyé Lónì

170

Ìyí Kòtò tí Ìdíje ife ẹ̀yẹ ilẹ̀ Áfríkà tí ọdún 2025 yóò wáyé lónìí ní olú ilé-iṣẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Ilẹ̀ Áfríkà ní Cairo, Egypt.

CAF sọ èyí dì mímọ nínú àlàyé kàn tó wà lórí ẹrọ́ ayélujára rẹ̀ nípasẹ Ẹka Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ní ọjọ́ Àjé.

Gẹ́gẹ́ bí ìgbìmọ̀ olùṣàkóso ṣé sọ, lẹ́yìn ìparí tí ẹlẹẹkẹ́rinlelọgbọ́n (34th) tí ìdíje náà, tí ‘TotalEnergies CAF AFCON, Morocco 2025, yóò wáyé ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun

Ìyí Kòtò náà yóò wáyé ní ago 14h00 (12h00 GMT).

Ọdún 2023 tí AFCON wáyé nílùú Côte d’Ivoire tí ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù náà sí borí Super Eagles tí Nàìjíríà ní ayò m2-1 ní ìparí ìdíje náà.

Comments are closed.

button