Take a fresh look at your lifestyle.

Brehme, Àgbábọ́ọ̀lù Ọmọ Germany Kú

160

Àgbábọ́ọ̀lù Ọmọ Orílẹ̀-èdè Germany tẹ́lẹ̀, Andreas Brehme, ẹní tí o gbá bọ́ọ̀lù sí àwọ̀n látí bóri ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ tó parí ife Àgbáyé tí 1990, kú ní ẹní ọgọ́ta ọdún lè mẹ́ta (63).

Brehme ló gbá bọ́ọ̀lù sàwọ̀n fún Germany látí bóri ìparí tí ìdíje Àgbáyé tí 1990 pẹ̀lú Argentina ní Rome.

Ó ṣójú Orílẹ̀-èdè rẹ̀ nígbà mẹ́rin dín làádọrun (86), o sí gbá adé Lìígì pẹ̀lú ìkọ bí Kaiserslautern, Bayern Munich àtí Inter Milan.

Comments are closed.

button