Take a fresh look at your lifestyle.

Àìsàn Jẹjẹrẹ Gba Ẹ̀mí Gbajúmọ̀ Òṣèré Obìnrin

160

 

Òsèré-bìnrin àti gbajumọ lori ẹrọ mohunmaworan, Ethel Aderemi-Ekpe ti jade laye. Ọ̀gá agba ile iṣẹ National Film and Video Censors Board (NFVCB), Dókítà Shaibu lo gbe ìròyìn yìí jade lori opo ayelujara Facebook rẹ.

Husseini ko bayi, “Ethel Ekpe, (Ethel Aderemi ọmọ Ekpe),
tó n mu inú àwọn ololufe re dun , to n se Segi nínú eré atijọ́, ere lori erọ mohunmaworan
Nigerian Television Authority(NTA) lati ọdọ Ken Saro Wiwa, ti wọn pé akọle rẹ ni
‘Basi and Company’, ti papò da”.

Iroyin roo pé o ku ni ọjo keje, ọjọ ojoru, oṣù Kejì, odun yìí.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button