Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Rọ Àwọn Amúlùúdùn Láti Gbé Àṣà Wa Lárugẹ.

606

Mínísítà fún àṣà, àti ìṣe wà, Amòfin Hannatu Musa Musawa tí gbà àwọn Amúlùúdùn Làmọ̀ràn láti túnbò teramọ́ ìdàgbàsókè Àṣà àti ìṣe wà ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Nínú ọ̀rọ̀ ìkíni ayẹyẹ a ku ẹwu ọdún ni ọ̀rọ̀ náà tí jáde.

Mínísítà ni òun fi àsìkò yìí dupẹ fún àwọn ọpọlọ àti ẹ̀bùn tí àwọn ènìyàn tí fí hàn sí ìdàgbàsókè àṣà àti ìṣe wà ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ó ní ìjọ wa, ewì wa,ati orin wa, mu àwọn ìtàn àti ìrántí tí kò lẹgbẹ wà láwùjọ, O ni o n mú wá mọ ará wá sí àti iṣẹ wa.

Ó ní gbogbo awọn àṣà àti ìṣe wà wọn yí, mú wa padà sí orísun wa, pàápàá jùlọ o mu ìfẹ́ àti ìrẹ́pọ̀ wà láàárin ará wá.

Ó  ní àwọn Amúlùúdùn lo ni iṣé to poju láti ṣe nípa titan imọlẹ si ni gbogbo ọ̀nà.

Comments are closed.

button