Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Iṣé Tó Mú Ìwúrí Dání Ẹlẹ́ẹ̀kẹ́ta Irú Rẹ.

0 116

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú Ìbáṣepọ̀ ilé iṣé Social Partner ni ọjọ́bọ̀ ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò ìsè to mú Ìwúrí wà Ẹlẹ́ẹ̀kẹ́ta Irú rẹ (DWCP) èyí tí yóò ṣiṣẹ́ láàrin ọdún 2023 sí ọdún 2027.

Ìlú Abuja ní àfilọ́lẹ̀ náà ti wáyé, ètò yìí wa láti ṣe atọ́nà fún ìjọba àti àwọn tọrọ kàn lórí bi àwọn òṣìṣẹ́ yóò ṣe ma Ṣíṣẹ́ ni agbègbè tó dùn wọ àti láti ṣe àwọn òṣìṣẹ́ wọn dáradára ni ọ̀nà ti ó tọ́ fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀rọ̀ ajé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ilé iṣé àwọn òṣìṣẹ́ Làgbáyé ILO sọ wí pé ètò yìí wà fún  àwọn ilé iṣé gbogbo ati awọn ìjọba láti di ìyà àti òsì kún ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti láti pèsè agbègbè àlàáfíà tí yóò mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀.

Wọn ni ètò náà ti o tí bẹ̀rẹ̀ láti oṣù mẹta ọdún 2021, nígbà tí Ìjọba àpapọ̀ ti ni ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ ILO.

Ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí Eustace Jame sójú fún ni gboyin gboyin ni àwọn wa lẹ́yìn ilé iṣé ILO fún ètò náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button