Take a fresh look at your lifestyle.

Ó Lé Ní Ọgọ́rin Àwọn Ènìyàn Tó Ní Àìsàn Ìtọ Suger Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

0 73

Àjọ tó ń mójú tó àìsàn Suger ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ni nínú ìwáàdí awọn, o tó Ọgọ́rin àwọn ènìyàn tó ni àìsàn ìtọ Suger, wọn ní lẹ́yìn àyẹ̀wò ni ọpọlọpọ tó mọ ipò ìlera rẹ.

Àyẹ̀wò yìí ni wọn ṣe fún àwọn ènìyàn káàkiri ilẹ Áfíríkà, Europe àti South America láti lee je ki won mọ ipò tí ìlera àwọn ènìyàn wa.

Bí ìròyìn ti fí tó wà létí, wọn ní àìsàn yìí n fa àisàn ọkan, àìsàn kidirin, àìsàn ojú àti bẹẹ bẹẹ lọ, wọn àìsàn to burú jù ní

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button