Take a fresh look at your lifestyle.

Ìrètí Ń Bẹ Fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà: Ìyàwó Ààrẹ Tinubu.

0 56

Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Oloremi Tinubu Sọ wí pé Ìrètí nlá n bẹ fún gbogbo àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ó ni labẹ àkọsọ ìjọba Bola Tinubu, ìrètí n be nitori àwọn ètò tí o n lọ lọwọ báyìí o da lẹ ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìyàwó Ààrẹ tó sọ̀rọ̀ nibi ayeye bí bu ọlá fún àwọn ènìyàn tó wà lókè òkun, Ó ní àlàáfíà àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ jẹ Ààrẹ lógún

Ìyàwó Ààrẹ Gbóríyìn fún àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíría ti n gbé ni Orílẹ̀-èdè Sierra Leone fun iṣọkan wọn.

Ààrẹ NIDO in Sierra Leone, Ògbéni Abiodun Oyebola, dupẹ lọwọ Ààrẹ Tinubu ati ìyàwó rẹ ni Orúkọ gbogbo àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíría ti o wà ní Sirra Leone.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button