Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ MNJTF Sọ Wí pé Niger  Sì Jẹ́ Ọmọ Ẹgbẹ́ Pàtàkì.

0 56

Ẹgbẹ́ MNJTF ti ìpele kẹrin sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ tó nlọ wí pé àwọn ki ṣe ọmọ ẹgbẹ́ MNJTF.

Alukoro fún fún ẹgbẹ́ MNJTF Abubakar Abdullahi, o ni ìròyìn náà tó àwọn létí láti ilẹ iṣé àwọn oníròyìn wí pé àwọn ki ṣe ọmọ ẹgbẹ́ MNJTF mọ.

Wọn ní ko sí ọjọ́ kan ti àwọn sọ èyí tàbí rọ láti kúrò nínú ẹgbẹ́ MNJTF wọn ní àwọn sí wa pẹ̀lú ẹgbẹ́ náà láti kojú ìwà ìbàjẹ́ láwùjọ.

Ó wà rọ àwọn oníròyìn láti wá òfin tótó ìròyìn ki wọn tó sọ sí ita

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button