Ilé iṣé tó ń jẹ Water and Environment Development (CWED) ní ọjọ́ ajé fún àwọn ọmọ ilé ìwé ìjọba ti Ìpínlẹ̀ Kaduna ni iledi fún nkan oṣù.
Nígbà tí o n bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀, Ìyáàfin Lydia Saleh sọ wí pé iṣẹ́ àwọn ni láti rí wí pé ile igbọnsẹ àwọn ilé ìwé wa ni mímọ́ tóní tóní.
Awọn ohun èlò míràn bí ọsẹ,búrọ́sì àwọn ohun míràn tí yóò mú ilé ìgbọ̀nsẹ̀ dáradára.
Ayẹyẹ yìí wa ń wáyé ni odoodun Làgbáyé, láti dènà àìsàn to lè jẹ yọ láti ilẹ ìgbọ̀nsẹ̀.
Ó wá rọ àwọn ọmọ ilé ìwé náà láti lo ànfààní náà dada.