Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìpínlẹ̀ Nasarawa Balarabe Abdullahi ti Kẹ́dùn Ikú ọ̀gagun to ti feyinti Chris Alli.
Nínú àtẹ̀jáde kàn to jáde láti ọwọ́ Akòwé ile ìgbìmọ̀ aṣòfin Jibrin Gwamna ni Lafia, o ṣàlàyé Ọ̀gagun náà gẹ́gẹ́ bí akínkanjú Ọkùnrin.
O ni ọkan lare olóyè àti alága fún ẹgbẹ́ ọmọ ìlú Ohiku -Egbira ni ìpínlẹ̀ Kogi
O wá gbàdúrà wí pé kí Ọlọrun di ebi náà mú kí o sì tẹ ṣi afẹfẹ réré.