Take a fresh look at your lifestyle.

Abẹ́rẹ́ àjẹsára HPV: Àwọn Onímọ̀ Rọ Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Yẹra Fún Ìròyìn Tí Kì Ṣe Òtítọ Nípa Abẹ́rẹ́ Náà.

0 54

Àwọn onímọ̀ Oníṣègùn òyìnbó ti ro àwọn Orílẹ̀-èdè Nàìjíría lati ko ẹtì ikún sí ìròyìn tí kò pé tó, èyí tí o n lọ lọ́wọ́ nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára HPV, ó ní abẹ́rẹ́ àjẹsára náà kò ní ẹwù kankan nínú fún àgọ́ ará, o ní pàápàá jùlọ lọ dènà àìsàn jẹjẹrẹ.

Níbi ìpàdé tí àwọn Oníròyìn nípa ìlera gbé kalẹ ní ọ̀rọ̀ náà tí wáyé, wọn ní ko ti sí akọ sile wí pé abẹ́rẹ́ àjẹsára náà mú àìsàn tabi jàmbá bá àgọ́ ará

Wọn ní kí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíría tọju ará wọn dáradára ki wọn máṣe gbà àwọn ìròyìn ìbànújẹ láàyè lati ṣe àkóbá fún àgọ́ ará wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button