Ikọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC ti ìpínlẹ̀ Plateau ti rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti ṣe àjọyọ̀ ìdájọ́ ilé-ejọ́ lórí ìbò gómìnà níwọ̀nba, láti máá dá wàhálà sílẹ̀.
Alaga rẹ, Oloye Rufus Bature, gba imọran yii ninu alaye kan ti Akọwe ipolongo ẹgbẹ fun ipinlẹ naa, Ọgbẹni Sylvanus Namang buwọ lu.
Ile-ẹjọ, ti o joko ni ọjọ Aiku, ni Abuja, da ibo Gomina Caleb Mutfwang nu ti o si kede Nentawe Yilwatda, ti APC gẹgẹ bi eni ti i jawe olubori.
Alaye naa sọ pe Bature ni Plateau le tun gbera sọ pada nigbẹyin.
Alaga wa gba imọran pe ki wọn fi ibinu ati ikorira ti o waye nipasẹ ibeere naa sẹyin, nitori pe wọn n ṣe yẹyẹ Plateau.
Bature tun wa rọ awọn ile-iṣẹ aabo lati fi oju wọn ṣọ ori nitori igbesẹ kankan to ba le fa irufin.
O wa ki Yilwatda ati igbakeji rẹ , Ọgbẹni Pam Bot-Mang, ku oriire lori aṣeyege wọn.