Take a fresh look at your lifestyle.

Ènìyàn Mẹ́jọ Pàdánù Ẹ̀mí Wọ́n Látári Ilẹ̀ Yiyá

0 138

Ènìyàn mẹ́jọ ló tí pàdánù ẹ̀mí wọ́n látári ìṣẹlẹ̀ ilẹ̀ yiyá tó ṣẹlẹ̀ ní gúúsù Orílẹ̀-èdè Philippines, àwọn ẹṣọ Ààbò tí orílẹ̀-èdè náà sọ.

Àwọn ènìyàn méjì tí wọ́n tí ń wá làkókò iṣẹlẹ̀ náà ní ọjọ́ Ẹtì ní Island Mindanao ní wọ́n tí jẹrisi ikú wọ́n, àwọn ẹṣọ Ààbò sọ.

Ìròyìn sọ pé àwọn tó kú láìpẹ́ ló wáyé ní àgbègbè Sarangani.

Nibayi, àwọn mìíràn tún kú nì South Cotabato àti àgbègbè Davao Occidental, làkókò tí àwọn ènìyàn mẹtala míràn 13 fí àràpà níbi iwarìri náà, èyítí o fí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sínú ìbẹrù, bí ilé àádọta ṣé tí wò.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button