Take a fresh look at your lifestyle.

Amẹ́ríkà, Ísráẹ́lì Àtí Hamas Tí Ṣé Àdéhùn Látí Dáwọ Ogún Dúró Fún Ìgbà Díẹ̀

0 139

Ìjọba Ísráẹ́lì, Amẹ́ríkà, àti Hamas tí ṣé àdéhùn látí dáwọ ogún dúró fún ìgbà díẹ̀ látí dá àwọn Obìnrin àti àwọn ọmọdé tó wà ní ìgbèkùn wọ́n ní Gaza ní paṣipaarọ fún ìdádúró ogún ọjọ́ márùn ùn, ìwé ìròyìn Washington Post.

Gẹ́gẹ́ bí apakan àlàyé náà, àdéhùn ojú-ìwé abala mẹ́fà náà ní, gbogbo àwọn ẹgbẹ́ méjèèjì yóò dáwọ dúró fún ó kéré jù ọjọ́ márùn pẹ̀lú ìpinnu láti máa fí àwon tó wà ní ihamọ wọ́n ṣọwọ́ ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan

A kò tí gbọ́ àlàyé látí ọdọ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè America tàbí ọfisi Alákóso tí Israel lórí ìròyìn yìí.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button