Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Tún Ṣé Ìlérí Látí Tún Ẹ̀kà Ẹ̀kọ́ Ṣé

0 189

Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ pé ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí pinnu láti tún gbogbo ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ṣé lorilẹ̀-èdè yìí láti gbé àwọn ọmọ ìlú tó kàwé dáadáa jáde.

Tinubu, tó jẹ́ Àlejò sí Yunifásítì tí Ibadan, UI, ṣé ìdánilójú náà níbí ayẹyẹ ọjọ́ kàrún lé laadọrin 75th idasilẹ tí ilé-ẹ̀kọ́ náà.

Àlejò náà ní Mínísítà tí ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tahir Mamman, sọ pé ìṣàkóso rẹ̀ ní òye ni kíkún lórí ètò ẹ̀kọ́ àti pé yóò mú àwọn ìmọ túntún tí yóò ṣé àtúnyẹwò gbogbo ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ní ìpele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button